Quran with Yoruba translation - Surah Maryam ayat 28 - مَريَم - Page - Juz 16
﴿يَٰٓأُخۡتَ هَٰرُونَ مَا كَانَ أَبُوكِ ٱمۡرَأَ سَوۡءٖ وَمَا كَانَتۡ أُمُّكِ بَغِيّٗا ﴾
[مَريَم: 28]
﴿ياأخت هارون ما كان أبوك امرأ سوء وما كانت أمك بغيا﴾ [مَريَم: 28]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Arábìnrin Hārūn, bàbá rẹ kì í ṣe ènìyàn burúkú. Àti pé ìyá rẹ kì í ṣe alágbèrè |