Quran with Yoruba translation - Surah Maryam ayat 94 - مَريَم - Page - Juz 16
﴿لَّقَدۡ أَحۡصَىٰهُمۡ وَعَدَّهُمۡ عَدّٗا ﴾
[مَريَم: 94]
﴿لقد أحصاهم وعدهم عدا﴾ [مَريَم: 94]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Dájúdájú (Allāhu) mọ̀ wọ́n. Ó sì ka òǹkà wọn tààrà |