Quran with Yoruba translation - Surah Maryam ayat 93 - مَريَم - Page - Juz 16
﴿إِن كُلُّ مَن فِي ٱلسَّمَٰوَٰتِ وَٱلۡأَرۡضِ إِلَّآ ءَاتِي ٱلرَّحۡمَٰنِ عَبۡدٗا ﴾
[مَريَم: 93]
﴿إن كل من في السموات والأرض إلا آتي الرحمن عبدا﴾ [مَريَم: 93]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Kò sí ẹnì kan nínú àwọn sánmọ̀ àti ilẹ̀ àyàfi kí ó wá bá Àjọkẹ́-ayé ní ipò ẹrúsìn |