Quran with Yoruba translation - Surah Al-Baqarah ayat 12 - البَقَرَة - Page - Juz 1
﴿أَلَآ إِنَّهُمۡ هُمُ ٱلۡمُفۡسِدُونَ وَلَٰكِن لَّا يَشۡعُرُونَ ﴾
[البَقَرَة: 12]
﴿ألا إنهم هم المفسدون ولكن لا يشعرون﴾ [البَقَرَة: 12]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Ẹ kíyè sí i! Dájúdájú àwọn gan-an ni òbìlẹ̀jẹ́, ṣùgbọ́n wọn kò fura |