Quran with Yoruba translation - Surah Al-Baqarah ayat 179 - البَقَرَة - Page - Juz 2
﴿وَلَكُمۡ فِي ٱلۡقِصَاصِ حَيَوٰةٞ يَٰٓأُوْلِي ٱلۡأَلۡبَٰبِ لَعَلَّكُمۡ تَتَّقُونَ ﴾
[البَقَرَة: 179]
﴿ولكم في القصاص حياة ياأولي الألباب لعلكم تتقون﴾ [البَقَرَة: 179]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Ìsẹ̀mí wà fun yín nínú (òfin) ìgbẹ̀san ìpànìyàn, ẹ̀yin onílàákáyè, kí ẹ lè bẹ̀rù (Allāhu) |