Quran with Yoruba translation - Surah Al-Baqarah ayat 42 - البَقَرَة - Page - Juz 1
﴿وَلَا تَلۡبِسُواْ ٱلۡحَقَّ بِٱلۡبَٰطِلِ وَتَكۡتُمُواْ ٱلۡحَقَّ وَأَنتُمۡ تَعۡلَمُونَ ﴾
[البَقَرَة: 42]
﴿ولا تلبسوا الحق بالباطل وتكتموا الحق وأنتم تعلمون﴾ [البَقَرَة: 42]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Ẹ má da irọ́ pọ̀ mọ́ òdodo, ẹ sì má fi òdodo pamọ́ nígbà tí ẹ̀yin mọ (òdodo) |