Quran with Yoruba translation - Surah Al-Baqarah ayat 43 - البَقَرَة - Page - Juz 1
﴿وَأَقِيمُواْ ٱلصَّلَوٰةَ وَءَاتُواْ ٱلزَّكَوٰةَ وَٱرۡكَعُواْ مَعَ ٱلرَّٰكِعِينَ ﴾
[البَقَرَة: 43]
﴿وأقيموا الصلاة وآتوا الزكاة واركعوا مع الراكعين﴾ [البَقَرَة: 43]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Ẹ kírun, ẹ yọ zakāh, kí ẹ sì dáwọ́ tẹ orúnkún pẹ̀lú àwọn olùdáwọ́tẹ-orúnkún (lórí ìrun) |