Quran with Yoruba translation - Surah Ta-Ha ayat 120 - طه - Page - Juz 16
﴿فَوَسۡوَسَ إِلَيۡهِ ٱلشَّيۡطَٰنُ قَالَ يَٰٓـَٔادَمُ هَلۡ أَدُلُّكَ عَلَىٰ شَجَرَةِ ٱلۡخُلۡدِ وَمُلۡكٖ لَّا يَبۡلَىٰ ﴾
[طه: 120]
﴿فوسوس إليه الشيطان قال ياآدم هل أدلك على شجرة الخلد وملك لا﴾ [طه: 120]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Ṣùgbọ́n Èṣù kó ròyíròyí bá a; ó wí pé: “Ādam, ǹjẹ́ mo lè júwe rẹ sí igi gbére àti ìjọba tí kò níí tán?” |