Quran with Yoruba translation - Surah Ta-Ha ayat 62 - طه - Page - Juz 16
﴿فَتَنَٰزَعُوٓاْ أَمۡرَهُم بَيۡنَهُمۡ وَأَسَرُّواْ ٱلنَّجۡوَىٰ ﴾
[طه: 62]
﴿فتنازعوا أمرهم بينهم وأسروا النجوى﴾ [طه: 62]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Wọ́n fọ̀rọ̀ jomi toro ọ̀rọ̀ láààrin ara wọn. Wọ́n sì tẹ̀ sọ̀rọ̀ |