Quran with Yoruba translation - Surah Ta-Ha ayat 84 - طه - Page - Juz 16
﴿قَالَ هُمۡ أُوْلَآءِ عَلَىٰٓ أَثَرِي وَعَجِلۡتُ إِلَيۡكَ رَبِّ لِتَرۡضَىٰ ﴾
[طه: 84]
﴿قال هم أولاء على أثري وعجلت إليك رب لترضى﴾ [طه: 84]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Ó sọ pé: “Àwọn nìwọ̀nyí tí wọ́n ń tọ orípa mi bọ̀ (lẹ́yìn mi). Èmi sì kánjú wá sọ́dọ̀ Rẹ nítorí kí O lè yọ́nú sí mi ni, Olúwa mi.” |