Quran with Yoruba translation - Surah Ta-Ha ayat 85 - طه - Page - Juz 16
﴿قَالَ فَإِنَّا قَدۡ فَتَنَّا قَوۡمَكَ مِنۢ بَعۡدِكَ وَأَضَلَّهُمُ ٱلسَّامِرِيُّ ﴾
[طه: 85]
﴿قال فإنا قد فتنا قومك من بعدك وأضلهم السامري﴾ [طه: 85]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni (Allāhu) sọ pé: "Dájúdájú Àwa ti dán ìjọ rẹ wò lẹ́yìn rẹ. Àti pé Sāmiriy ṣì wọ́n lọ́nà |