Quran with Yoruba translation - Surah Ta-Ha ayat 91 - طه - Page - Juz 16
﴿قَالُواْ لَن نَّبۡرَحَ عَلَيۡهِ عَٰكِفِينَ حَتَّىٰ يَرۡجِعَ إِلَيۡنَا مُوسَىٰ ﴾
[طه: 91]
﴿قالوا لن نبرح عليه عاكفين حتى يرجع إلينا موسى﴾ [طه: 91]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Wọ́n wí pé: “A ò níí yé dúró sọ́dọ̀ rẹ̀ títí (Ànábì) Mūsā yóò fi padà sọ́dọ̀ wa.” |