Quran with Yoruba translation - Surah Ta-Ha ayat 92 - طه - Page - Juz 16
﴿قَالَ يَٰهَٰرُونُ مَا مَنَعَكَ إِذۡ رَأَيۡتَهُمۡ ضَلُّوٓاْ ﴾
[طه: 92]
﴿قال ياهارون ما منعك إذ رأيتهم ضلوا﴾ [طه: 92]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni (Ànábì) Mūsā sọ pé: "Hārūn, kí ni ó kọ̀ fún ọ nígbà tí o rí wọn tí wọ́n ṣìnà |