×

Ipaya t’o tobi julo ko nii ba won ninu je. Awon molaika 21:103 Yoruba translation

Quran infoYorubaSurah Al-Anbiya’ ⮕ (21:103) ayat 103 in Yoruba

21:103 Surah Al-Anbiya’ ayat 103 in Yoruba (اليوربا)

Quran with Yoruba translation - Surah Al-Anbiya’ ayat 103 - الأنبيَاء - Page - Juz 17

﴿لَا يَحۡزُنُهُمُ ٱلۡفَزَعُ ٱلۡأَكۡبَرُ وَتَتَلَقَّىٰهُمُ ٱلۡمَلَٰٓئِكَةُ هَٰذَا يَوۡمُكُمُ ٱلَّذِي كُنتُمۡ تُوعَدُونَ ﴾
[الأنبيَاء: 103]

Ipaya t’o tobi julo ko nii ba won ninu je. Awon molaika yoo maa pade won, (won yoo so pe): “Eyi ni ojo yin ti A n se ni adehun fun yin.”

❮ Previous Next ❯

ترجمة: لا يحزنهم الفزع الأكبر وتتلقاهم الملائكة هذا يومكم الذي كنتم توعدون, باللغة اليوربا

﴿لا يحزنهم الفزع الأكبر وتتلقاهم الملائكة هذا يومكم الذي كنتم توعدون﴾ [الأنبيَاء: 103]

Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni
Ìpáyà t’ó tóbi jùlọ kò níí bà wọ́n nínú jẹ́. Àwọn mọlāika yóò máa pàdé wọn, (wọn yóò sọ pé): “Èyí ni ọjọ́ yín tí À ń ṣe ní àdéhùn fun yín.”
❮ Previous Next ❯

Verse in more languages

Transliteration Bangla Bosnian German English Persian French Hindi Indonesian Kazakh Dutch Russian Spanish Turkish Urdu Uzbek