Quran with Yoruba translation - Surah Al-Anbiya’ ayat 102 - الأنبيَاء - Page - Juz 17
﴿لَا يَسۡمَعُونَ حَسِيسَهَاۖ وَهُمۡ فِي مَا ٱشۡتَهَتۡ أَنفُسُهُمۡ خَٰلِدُونَ ﴾
[الأنبيَاء: 102]
﴿لا يسمعون حسيسها وهم في ما اشتهت أنفسهم خالدون﴾ [الأنبيَاء: 102]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Wọn kò sì níí gbọ́ kíkùn rẹ̀. Olùṣegbére sì ni wọ́n nínú ìgbádùn tí ẹ̀mí wọn ń fẹ́ |