Quran with Yoruba translation - Surah Al-Anbiya’ ayat 109 - الأنبيَاء - Page - Juz 17
﴿فَإِن تَوَلَّوۡاْ فَقُلۡ ءَاذَنتُكُمۡ عَلَىٰ سَوَآءٖۖ وَإِنۡ أَدۡرِيٓ أَقَرِيبٌ أَم بَعِيدٞ مَّا تُوعَدُونَ ﴾
[الأنبيَاء: 109]
﴿فإن تولوا فقل آذنتكم على سواء وإن أدري أقريب أم بعيد ما﴾ [الأنبيَاء: 109]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Tí wọ́n bá gbúnrí, sọ nígbà náà pé: "Èmi ń fi to yín létí pé èmi àti ẹ̀yin dì jọ dá dúró fún ogun ẹ̀sìn (tí ó máa ṣẹlẹ̀ láààrin wa báyìí). Èmi kò sì mọ̀ bóyá ohun tí Wọ́n ń ṣe ní àdéhùn fun yín ti súnmọ́ tàbí ó sì jìnnà |