Quran with Yoruba translation - Surah Al-Anbiya’ ayat 110 - الأنبيَاء - Page - Juz 17
﴿إِنَّهُۥ يَعۡلَمُ ٱلۡجَهۡرَ مِنَ ٱلۡقَوۡلِ وَيَعۡلَمُ مَا تَكۡتُمُونَ ﴾
[الأنبيَاء: 110]
﴿إنه يعلم الجهر من القول ويعلم ما تكتمون﴾ [الأنبيَاء: 110]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Dájúdájú (Allāhu) mọ ohun tí ó hàn nínú ọ̀rọ̀. Ó sì mọ ohun tí ẹ̀ ń fi pamọ́ |