Quran with Yoruba translation - Surah Al-Anbiya’ ayat 42 - الأنبيَاء - Page - Juz 17
﴿قُلۡ مَن يَكۡلَؤُكُم بِٱلَّيۡلِ وَٱلنَّهَارِ مِنَ ٱلرَّحۡمَٰنِۚ بَلۡ هُمۡ عَن ذِكۡرِ رَبِّهِم مُّعۡرِضُونَ ﴾
[الأنبيَاء: 42]
﴿قل من يكلؤكم بالليل والنهار من الرحمن بل هم عن ذكر ربهم﴾ [الأنبيَاء: 42]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Sọ pé: "Ta ni ẹni tí ó ń ṣọ yín ní òru àti ní ọ̀sán níbi ìyà Àjọkẹ́-ayé?" Àmọ́ ńṣe ni wọ́n ń gbúnrí kúrò níbi ìrántí Àjọkẹ́-ayé |