Quran with Yoruba translation - Surah Al-Anbiya’ ayat 50 - الأنبيَاء - Page - Juz 17
﴿وَهَٰذَا ذِكۡرٞ مُّبَارَكٌ أَنزَلۡنَٰهُۚ أَفَأَنتُمۡ لَهُۥ مُنكِرُونَ ﴾
[الأنبيَاء: 50]
﴿وهذا ذكر مبارك أنـزلناه أفأنتم له منكرون﴾ [الأنبيَاء: 50]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Èyí sì ni ìrántí oníbùkún tí A sọ̀kalẹ̀. Ṣé ẹ̀yin yóò takò ó ni |