Quran with Yoruba translation - Surah Al-Anbiya’ ayat 51 - الأنبيَاء - Page - Juz 17
﴿۞ وَلَقَدۡ ءَاتَيۡنَآ إِبۡرَٰهِيمَ رُشۡدَهُۥ مِن قَبۡلُ وَكُنَّا بِهِۦ عَٰلِمِينَ ﴾
[الأنبيَاء: 51]
﴿ولقد آتينا إبراهيم رشده من قبل وكنا به عالمين﴾ [الأنبيَاء: 51]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Dájúdájú A ti fún (Ànábì) ’Ibrọ̄hīm ní ìmọ̀nà tirẹ̀ ṣíwájú (kí ó tó dàgbà). Àwa sì ń jẹ́ Onímọ̀ nípa rẹ̀ |