Quran with Yoruba translation - Surah Al-Anbiya’ ayat 49 - الأنبيَاء - Page - Juz 17
﴿ٱلَّذِينَ يَخۡشَوۡنَ رَبَّهُم بِٱلۡغَيۡبِ وَهُم مِّنَ ٱلسَّاعَةِ مُشۡفِقُونَ ﴾
[الأنبيَاء: 49]
﴿الذين يخشون ربهم بالغيب وهم من الساعة مشفقون﴾ [الأنبيَاء: 49]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni (Àwọn ni) àwọn t’ó ń páyà Olúwa wọn ní ìkọ̀kọ̀. Olùpáyà sì ni wọ́n nípa Àkókò náà |