Quran with Yoruba translation - Surah Al-Anbiya’ ayat 58 - الأنبيَاء - Page - Juz 17
﴿فَجَعَلَهُمۡ جُذَٰذًا إِلَّا كَبِيرٗا لَّهُمۡ لَعَلَّهُمۡ إِلَيۡهِ يَرۡجِعُونَ ﴾
[الأنبيَاء: 58]
﴿فجعلهم جذاذا إلا كبيرا لهم لعلهم إليه يرجعون﴾ [الأنبيَاء: 58]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Ó sì fọ́ wọn sí wẹ́wẹ́ àfi àgbà (òrìṣà) wọn nítorí kí wọ́n lè padà dé bá a |