Quran with Yoruba translation - Surah Al-Anbiya’ ayat 57 - الأنبيَاء - Page - Juz 17
﴿وَتَٱللَّهِ لَأَكِيدَنَّ أَصۡنَٰمَكُم بَعۡدَ أَن تُوَلُّواْ مُدۡبِرِينَ ﴾
[الأنبيَاء: 57]
﴿وتالله لأكيدن أصنامكم بعد أن تولوا مدبرين﴾ [الأنبيَاء: 57]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Àti pé mo fi Allāhu búra, dájúdájú mo máa dète sí àwọn òrìṣà yín lẹ́yìn tí ẹ bá pẹ̀yìn dà, tí ẹ lọ |