Quran with Yoruba translation - Surah Al-Anbiya’ ayat 59 - الأنبيَاء - Page - Juz 17
﴿قَالُواْ مَن فَعَلَ هَٰذَا بِـَٔالِهَتِنَآ إِنَّهُۥ لَمِنَ ٱلظَّٰلِمِينَ ﴾
[الأنبيَاء: 59]
﴿قالوا من فعل هذا بآلهتنا إنه لمن الظالمين﴾ [الأنبيَاء: 59]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Wọ́n wí pé: “Ta ni ó ṣe èyí pẹ̀lú àwọn ọlọ́hun wa? Dájúdájú onítọ̀un wà nínú àwọn alábòsí.” |