Quran with Yoruba translation - Surah Al-Anbiya’ ayat 60 - الأنبيَاء - Page - Juz 17
﴿قَالُواْ سَمِعۡنَا فَتٗى يَذۡكُرُهُمۡ يُقَالُ لَهُۥٓ إِبۡرَٰهِيمُ ﴾
[الأنبيَاء: 60]
﴿قالوا سمعنا فتى يذكرهم يقال له إبراهيم﴾ [الأنبيَاء: 60]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Wọ́n wí pé: “A gbọ́ tí ọ̀dọ́kùnrin kan ń bu ẹnu àtẹ́ lù wọ́n. Wọ́n ń pe (ọmọ náà) ní ’Ibrọ̄hīm.” |