Quran with Yoruba translation - Surah Al-Anbiya’ ayat 61 - الأنبيَاء - Page - Juz 17
﴿قَالُواْ فَأۡتُواْ بِهِۦ عَلَىٰٓ أَعۡيُنِ ٱلنَّاسِ لَعَلَّهُمۡ يَشۡهَدُونَ ﴾
[الأنبيَاء: 61]
﴿قالوا فأتوا به على أعين الناس لعلهم يشهدون﴾ [الأنبيَاء: 61]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Wọ́n wí pé: “Ẹ mú un wá han àwọn ènìyàn kí wọ́n lè jẹ́rìí lé e lórí.” |