Quran with Yoruba translation - Surah Al-Anbiya’ ayat 95 - الأنبيَاء - Page - Juz 17
﴿وَحَرَٰمٌ عَلَىٰ قَرۡيَةٍ أَهۡلَكۡنَٰهَآ أَنَّهُمۡ لَا يَرۡجِعُونَ ﴾
[الأنبيَاء: 95]
﴿وحرام على قرية أهلكناها أنهم لا يرجعون﴾ [الأنبيَاء: 95]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Èèwọ̀ ni fún ará ìlú kan tí A ti parẹ́ (pé kí ó tún padà sí ayé); dájúdájú wọn kò níí padà mọ́ (sí ilé ayé) |