Quran with Yoruba translation - Surah Al-hajj ayat 20 - الحج - Page - Juz 17
﴿يُصۡهَرُ بِهِۦ مَا فِي بُطُونِهِمۡ وَٱلۡجُلُودُ ﴾
[الحج: 20]
﴿يصهر به ما في بطونهم والجلود﴾ [الحج: 20]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Wọ́n máa fi yọ́ ohun tí ń bẹ nínú ikùn wọn àti awọ ara wọn |