Quran with Yoruba translation - Surah Al-hajj ayat 64 - الحج - Page - Juz 17
﴿لَّهُۥ مَا فِي ٱلسَّمَٰوَٰتِ وَمَا فِي ٱلۡأَرۡضِۚ وَإِنَّ ٱللَّهَ لَهُوَ ٱلۡغَنِيُّ ٱلۡحَمِيدُ ﴾
[الحج: 64]
﴿له ما في السموات وما في الأرض وإن الله لهو الغني الحميد﴾ [الحج: 64]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni TiRẹ̀ ni ohunkóhun t’ó wà nínú àwọn sánmọ̀ àti ohunkóhun t’ó wà nínú ilẹ̀. Dájúdájú Allāhu, Òun mà ni Ọlọ́rọ̀, Ọlọ́pẹ́ |