Quran with Yoruba translation - Surah Al-hajj ayat 74 - الحج - Page - Juz 17
﴿مَا قَدَرُواْ ٱللَّهَ حَقَّ قَدۡرِهِۦٓۚ إِنَّ ٱللَّهَ لَقَوِيٌّ عَزِيزٌ ﴾
[الحج: 74]
﴿ما قدروا الله حق قدره إن الله لقوي عزيز﴾ [الحج: 74]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Wọn kò bu ọ̀wọ̀ fún Allāhu ní ọ̀wọ̀ tí ó tọ́ sí I. Dájúdájú Allāhu mà ni Alágbára, Olùborí |