Quran with Yoruba translation - Surah Al-Mu’minun ayat 116 - المؤمنُون - Page - Juz 18
﴿فَتَعَٰلَى ٱللَّهُ ٱلۡمَلِكُ ٱلۡحَقُّۖ لَآ إِلَٰهَ إِلَّا هُوَ رَبُّ ٱلۡعَرۡشِ ٱلۡكَرِيمِ ﴾
[المؤمنُون: 116]
﴿فتعالى الله الملك الحق لا إله إلا هو رب العرش الكريم﴾ [المؤمنُون: 116]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Nítorí náà, Allāhu Ọba Òdodo ga. Kò sí ọlọ́hun tí ìjọ́sìn tọ́ sí àfi Òun, Olúwa Ìtẹ́ alápọ̀n-ọ́nlé |