Quran with Yoruba translation - Surah Al-Mu’minun ayat 25 - المؤمنُون - Page - Juz 18
﴿إِنۡ هُوَ إِلَّا رَجُلُۢ بِهِۦ جِنَّةٞ فَتَرَبَّصُواْ بِهِۦ حَتَّىٰ حِينٖ ﴾
[المؤمنُون: 25]
﴿إن هو إلا رجل به جنة فتربصوا به حتى حين﴾ [المؤمنُون: 25]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Kò jẹ́ kiní kan bí kò ṣe ọkùnrin kan tí àlùjànnú ń bẹ lára rẹ̀. Nítorí náà, ẹ máa retí (ìkángun) rẹ̀ títí di ìgbà kan ná.” |