×

Ati pe A ko labo emi kan lorun afi iwon agbara re. 23:62 Yoruba translation

Quran infoYorubaSurah Al-Mu’minun ⮕ (23:62) ayat 62 in Yoruba

23:62 Surah Al-Mu’minun ayat 62 in Yoruba (اليوربا)

Quran with Yoruba translation - Surah Al-Mu’minun ayat 62 - المؤمنُون - Page - Juz 18

﴿وَلَا نُكَلِّفُ نَفۡسًا إِلَّا وُسۡعَهَاۚ وَلَدَيۡنَا كِتَٰبٞ يَنطِقُ بِٱلۡحَقِّ وَهُمۡ لَا يُظۡلَمُونَ ﴾
[المؤمنُون: 62]

Ati pe A ko labo emi kan lorun afi iwon agbara re. Tira kan t’o n so ododo (nipa ise eda) n be lodo Wa. A o si nii sabosi si won

❮ Previous Next ❯

ترجمة: ولا نكلف نفسا إلا وسعها ولدينا كتاب ينطق بالحق وهم لا يظلمون, باللغة اليوربا

﴿ولا نكلف نفسا إلا وسعها ولدينا كتاب ينطق بالحق وهم لا يظلمون﴾ [المؤمنُون: 62]

Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni
Àti pé A kò làbọ ẹ̀mí kan lọ́rùn àfi ìwọ̀n agbára rẹ̀. Tírà kan t’ó ń sọ òdodo (nípa iṣẹ́ ẹ̀dá) ń bẹ lọ́dọ̀ Wa. A ò sì níí ṣàbòsí sí wọn
❮ Previous Next ❯

Verse in more languages

Transliteration Bangla Bosnian German English Persian French Hindi Indonesian Kazakh Dutch Russian Spanish Turkish Urdu Uzbek