Quran with Yoruba translation - Surah Al-Mu’minun ayat 61 - المؤمنُون - Page - Juz 18
﴿أُوْلَٰٓئِكَ يُسَٰرِعُونَ فِي ٱلۡخَيۡرَٰتِ وَهُمۡ لَهَا سَٰبِقُونَ ﴾
[المؤمنُون: 61]
﴿أولئك يسارعون في الخيرات وهم لها سابقون﴾ [المؤمنُون: 61]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni àwọn wọ̀nyẹn ni wọ́n ń yára ṣe àwọn iṣẹ́ rere. Àwọn sì ni aṣíwájú nínú (àwọn ẹ̀san) iṣẹ́ náà |