Quran with Yoruba translation - Surah Al-Mu’minun ayat 90 - المؤمنُون - Page - Juz 18
﴿بَلۡ أَتَيۡنَٰهُم بِٱلۡحَقِّ وَإِنَّهُمۡ لَكَٰذِبُونَ ﴾
[المؤمنُون: 90]
﴿بل أتيناهم بالحق وإنهم لكاذبون﴾ [المؤمنُون: 90]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Àmọ́ sá, òdodo ni A mú wá ba wọn. Dájúdájú àwọn sì ni òpùrọ́ |