Quran with Yoruba translation - Surah Al-Mu’minun ayat 89 - المؤمنُون - Page - Juz 18
﴿سَيَقُولُونَ لِلَّهِۚ قُلۡ فَأَنَّىٰ تُسۡحَرُونَ ﴾
[المؤمنُون: 89]
﴿سيقولون لله قل فأنى تسحرون﴾ [المؤمنُون: 89]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Wọ́n á wí pé: “Ti Allāhu ni.” Sọ pé: “Nítorí náà, báwo ni wọ́n ṣe ń dan yín?” |