Quran with Yoruba translation - Surah Al-Furqan ayat 1 - الفُرقَان - Page - Juz 18
﴿تَبَارَكَ ٱلَّذِي نَزَّلَ ٱلۡفُرۡقَانَ عَلَىٰ عَبۡدِهِۦ لِيَكُونَ لِلۡعَٰلَمِينَ نَذِيرًا ﴾
[الفُرقَان: 1]
﴿تبارك الذي نـزل الفرقان على عبده ليكون للعالمين نذيرا﴾ [الفُرقَان: 1]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Ìbùkún ni fún Ẹni tí Ó sọ ọ̀rọ̀-ìpínyà (ohun t’ó ń ṣèpínyà láààrin òdodo àti irọ́) kalẹ̀ fún ẹrúsìn Rẹ̀ nítorí kí ó lè jẹ́ olùkìlọ̀ fún gbogbo ẹ̀dá |