Quran with Yoruba translation - Surah Al-Furqan ayat 11 - الفُرقَان - Page - Juz 18
﴿بَلۡ كَذَّبُواْ بِٱلسَّاعَةِۖ وَأَعۡتَدۡنَا لِمَن كَذَّبَ بِٱلسَّاعَةِ سَعِيرًا ﴾
[الفُرقَان: 11]
﴿بل كذبوا بالساعة وأعتدنا لمن كذب بالساعة سعيرا﴾ [الفُرقَان: 11]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Ńṣe ni wọ́n pe Àkókò náà nírọ́. A sì ti pèsè Iná t’ó ń jò sílẹ̀ de ẹnikẹ́ni tí ó bá pe Àkókò náà nírọ́ |