Quran with Yoruba translation - Surah Al-Furqan ayat 12 - الفُرقَان - Page - Juz 18
﴿إِذَا رَأَتۡهُم مِّن مَّكَانِۭ بَعِيدٖ سَمِعُواْ لَهَا تَغَيُّظٗا وَزَفِيرٗا ﴾
[الفُرقَان: 12]
﴿إذا رأتهم من مكان بعيد سمعوا لها تغيظا وزفيرا﴾ [الفُرقَان: 12]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Nígbà tí (Iná náà) bá rí wọn láti àyè kan tí ó jìnnà, wọn yó sì máa gbọ́ ohùn ìbínú àti kíkùn (rẹ̀) |