Quran with Yoruba translation - Surah Al-Furqan ayat 33 - الفُرقَان - Page - Juz 19
﴿وَلَا يَأۡتُونَكَ بِمَثَلٍ إِلَّا جِئۡنَٰكَ بِٱلۡحَقِّ وَأَحۡسَنَ تَفۡسِيرًا ﴾
[الفُرقَان: 33]
﴿ولا يأتونك بمثل إلا جئناك بالحق وأحسن تفسيرا﴾ [الفُرقَان: 33]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Wọn kò níí mú àpẹẹrẹ kan wá fún ọ (bí ìbéèrè láti fi takò ọ́) àfi kí Á mú òdodo (ìyẹn, al-ƙur’ān) àti àlàyé t’ó dára jùlọ wá fún ọ (lórí rẹ̀) |