Quran with Yoruba translation - Surah Al-Furqan ayat 62 - الفُرقَان - Page - Juz 19
﴿وَهُوَ ٱلَّذِي جَعَلَ ٱلَّيۡلَ وَٱلنَّهَارَ خِلۡفَةٗ لِّمَنۡ أَرَادَ أَن يَذَّكَّرَ أَوۡ أَرَادَ شُكُورٗا ﴾
[الفُرقَان: 62]
﴿وهو الذي جعل الليل والنهار خلفة لمن أراد أن يذكر أو أراد﴾ [الفُرقَان: 62]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Òun ni Ẹni tí Ó ṣe òru àti ọ̀sán ní ìtẹ̀léǹtẹ̀lé (tí ìkíní yàtọ̀ sí ìkejì) nítorí ẹni tí ó bá gbèrò láti ṣe ìrántí (Allāhu) tàbí tí ó bá gbèrò ìdúpẹ́ (fún Un) |