Quran with Yoruba translation - Surah Al-Furqan ayat 69 - الفُرقَان - Page - Juz 19
﴿يُضَٰعَفۡ لَهُ ٱلۡعَذَابُ يَوۡمَ ٱلۡقِيَٰمَةِ وَيَخۡلُدۡ فِيهِۦ مُهَانًا ﴾
[الفُرقَان: 69]
﴿يضاعف له العذاب يوم القيامة ويخلد فيه مهانا﴾ [الفُرقَان: 69]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni A óò ṣe ìyà ní ìlọ́po fún un ní Ọjọ́ Àjíǹde. Ó sì máa ṣe gbére nínú rẹ̀ ní ẹni yẹpẹrẹ |