Quran with Yoruba translation - Surah Al-Furqan ayat 71 - الفُرقَان - Page - Juz 19
﴿وَمَن تَابَ وَعَمِلَ صَٰلِحٗا فَإِنَّهُۥ يَتُوبُ إِلَى ٱللَّهِ مَتَابٗا ﴾
[الفُرقَان: 71]
﴿ومن تاب وعمل صالحا فإنه يتوب إلى الله متابا﴾ [الفُرقَان: 71]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Ẹnikẹ́ni tí ó bá ronú pìwàdà, tí ó sì ṣe iṣẹ́ rere, (kí ó mọ̀) pé dájúdájú ó ń ronú pìwàdà pátápátá sọ́dọ̀ Allāhu ni |