Quran with Yoruba translation - Surah Ash-Shu‘ara’ ayat 130 - الشعراء - Page - Juz 19
﴿وَإِذَا بَطَشۡتُم بَطَشۡتُمۡ جَبَّارِينَ ﴾
[الشعراء: 130]
﴿وإذا بطشتم بطشتم جبارين﴾ [الشعراء: 130]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Nígbà tí ẹ bá sì gbá (ènìyàn mú láti fìyà jẹ wọ́n), ẹ̀ ń gbá wọn mú ní ìgbámú aláìlójú-àánú |