Quran with Yoruba translation - Surah Ash-Shu‘ara’ ayat 139 - الشعراء - Page - Juz 19
﴿فَكَذَّبُوهُ فَأَهۡلَكۡنَٰهُمۡۚ إِنَّ فِي ذَٰلِكَ لَأٓيَةٗۖ وَمَا كَانَ أَكۡثَرُهُم مُّؤۡمِنِينَ ﴾
[الشعراء: 139]
﴿فكذبوه فأهلكناهم إن في ذلك لآية وما كان أكثرهم مؤمنين﴾ [الشعراء: 139]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Nítorí náà, wọ́n pè é ní òpùrọ́. A sì pa wọ́n run. Dájúdájú àmì wà nínú ìyẹn. Ọ̀pọ̀lọ́pọ̀ wọn ni kò sì jẹ́ onígbàgbọ́ òdodo |