Quran with Yoruba translation - Surah Ash-Shu‘ara’ ayat 27 - الشعراء - Page - Juz 19
﴿قَالَ إِنَّ رَسُولَكُمُ ٱلَّذِيٓ أُرۡسِلَ إِلَيۡكُمۡ لَمَجۡنُونٞ ﴾
[الشعراء: 27]
﴿قال إن رسولكم الذي أرسل إليكم لمجنون﴾ [الشعراء: 27]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni (Fir‘aon) wí pé: “Dájúdájú Òjíṣẹ́ yín èyí tí wọ́n rán si yín, wèrè mà ni.” |