Quran with Yoruba translation - Surah An-Naml ayat 31 - النَّمل - Page - Juz 19
﴿أَلَّا تَعۡلُواْ عَلَيَّ وَأۡتُونِي مُسۡلِمِينَ ﴾
[النَّمل: 31]
﴿ألا تعلوا علي وأتوني مسلمين﴾ [النَّمل: 31]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Kí ẹ má ṣègbéraga sí mi, kí ẹ sì wá sí ọ̀dọ̀ mi (láti di) mùsùlùmí.” |