Quran with Yoruba translation - Surah An-Naml ayat 30 - النَّمل - Page - Juz 19
﴿إِنَّهُۥ مِن سُلَيۡمَٰنَ وَإِنَّهُۥ بِسۡمِ ٱللَّهِ ٱلرَّحۡمَٰنِ ٱلرَّحِيمِ ﴾
[النَّمل: 30]
﴿إنه من سليمان وإنه بسم الله الرحمن الرحيم﴾ [النَّمل: 30]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Dájúdájú ó wá láti ọ̀dọ̀ (Ànábì) Sulaemọ̄n. Dájúdájú ó (sọ pé) “Ní orúkọ Allāhu, Àjọkẹ́-ayé, Àṣàkẹ́-ọ̀run |