Quran with Yoruba translation - Surah An-Naml ayat 85 - النَّمل - Page - Juz 20
﴿وَوَقَعَ ٱلۡقَوۡلُ عَلَيۡهِم بِمَا ظَلَمُواْ فَهُمۡ لَا يَنطِقُونَ ﴾
[النَّمل: 85]
﴿ووقع القول عليهم بما ظلموا فهم لا ينطقون﴾ [النَّمل: 85]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Ọ̀rọ̀ náà sì kò lé wọn lórí nítorí pé wọ́n ṣàbòsí. Wọn kò sì níí sọ̀rọ̀ |