Quran with Yoruba translation - Surah Al-Qasas ayat 17 - القَصَص - Page - Juz 20
﴿قَالَ رَبِّ بِمَآ أَنۡعَمۡتَ عَلَيَّ فَلَنۡ أَكُونَ ظَهِيرٗا لِّلۡمُجۡرِمِينَ ﴾
[القَصَص: 17]
﴿قال رب بما أنعمت علي فلن أكون ظهيرا للمجرمين﴾ [القَصَص: 17]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Ó sọ pé: “Olúwa mi, fún wí pé O ti ṣe ìkẹ́ fún mi, èmi kò níí jẹ́ olùrànlọ́wọ́ fún àwọn ẹlẹ́ṣẹ̀.” |